歌词

Máà lékè wọn
Máà lékè wọn
Máà lékè wọn-
(It's Protunez on the beat)

Mo dò ṣí bàtà tí lékè odò o
Ẹjá arọ ń bẹ nísàlẹ odò o
Má f'ẹjá bọ'rí, gbé mi lékè wọn
Ìgbàgbọ mí tí mú mi lára dá
Gbogbo àgbára tí yí po padà, ahh
Mo tí lékè wọn

Now, I'm grinding, my enemies are crawling
Some dey beside me, but never see me coming
My train is nonstop, don't ever try to cross me
Ah, mo tí lékè wọn

I know, power must change hands right now
They know, ẹlẹmi lo má last right now
B'okun o rú, b'ọsa o rú
Ìwọ là má lékè wọn
B'okun o rú, b'ọsa o ru
Àwa là má lékè wọn
Ọmọ to ń pá'dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lolè ṣána
Ọmọ to ń pá'dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lolè ṣana

Mo kọ tá, mo kòpée, ọtá ń jẹ
Pé ò gbọdọ fọ'hùn
Ọmọ tó ń pá'wó, tọ ń ṣiṣẹ́
Ò gbọdọ májẹ ìgbádùn
Ojú ẹnì má lá, dandan ní arí ìyọnu
Áìfaila ọjọ, t'ọjọ bálá, máa làá

Now, I'm grinding, my enemies are crawling
Some dey beside me, but never see me coming
My train is nonstop, don't ever try to cross me
Ahh, mo tí lékè wọn

I know (má lékè wọn), power must change hands right now (ìyá wọn, bàbá wọn)
They know, ẹlẹmi lo má last right now
B'okun o rú (b'owó ru), b'ọsa o rú (b'owó ru)
Ìwọ là má lékè wọn (à má lékè wọn)
B'okun o rú, b'ọsa o rú
Àwa là má lékè wọn (eh-eh-eh-ehh)
Ọmọ tó ń pá'dán (ọmọ), idán gan-gan idán (ko má pá'dán lọ)
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lolè ṣana
Ọmọ to ń pá'dán, idán gan-gan idán
Ọmọ to ń pá'wó, ìwọ lolè ṣanaa

Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande

API Calls

从 Spotify 记录音乐?

将您的 Spotify 帐户连接到您的 Last.fm 帐户,通过任何设备或平台上的任何 Spotify 应用记录您所听的一切内容。

连接到 Spotify

关闭